Psalms 68:27 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ wo Bẹnjamini tí ó kéré jù níwájú, ẹ wo ogunlọ́gọ̀ àwọn ìjòyè Juda, ẹ wo àwọn ìjòyè Sebuluni ati ti Nafutali.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nibẹ ni Benjamini kekere wà, pẹlu olori wọn, awọn ọmọ-alade Juda pẹlu awọn igbimọ wọn, awọn ọmọ-alade Sebuloni, ati awọn ọmọ-alade Naftali.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Níbẹ̀ ní ẹ̀yà kékeré Bẹ́ńjámínì wà, tí o ń darí wọn, níbẹ̀ ni àwọn ọmọ aládé Júdà, níbẹ̀ ni àwọn ọmọ aládé Sébúlúnì àti tí Náfútàlì.