Psalms 68:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn kí inú àwọn olódodo máa dùn, kí wọn máa yọ̀ níwájú Ọlọrun; kí wọn máa yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn jẹ ki inu awọn olododo ki o dùn; ki nwọn ki o yọ̀ niwaju Ọlọrun. nitõtọ, ki nwọn ki o yọ̀ gidigidi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n kí inú olódodo kí ó dùn kí ó sì kún fún ayọ̀ níwájú Ọlọ́run; kí inú wọn kí ó dùn, kí ó sì kún fún ayọ̀.