Psalms 68:30 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bá àwọn ẹranko ẹ̀dá tí ń gbé inú èèsún ní Ijipti wí; àwọn akọ mààlúù, láàrin agbo ẹran àwọn orílẹ̀-èdè. Tẹ àwọn tí ó fẹ́ràn owó mọ́lẹ̀; fọ́n àwọn orílẹ̀-èdè tí ó fẹ́ràn ogun ká.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ba awọn ẹranko ẽsu wi, ọ̀pọlọpọ awọn akọ-malu, pẹlu awọn ọmọ-malu enia, titi olukulùku yio fi foribalẹ pẹlu ìwọn fadaka: tú awọn enia ti nṣe inu didùn si ogun ka.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bá àwọn ẹranko búburú wí, tí ń gbé láàrin ìko ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn akọ màlúù pẹ̀lú àwọn ọmọ màlúù títí olúkúlùkù yóò fi forí balẹ̀ pẹ̀lú ìwọn fàdákà: tú àwọn orílẹ̀-èdè ti ń ṣe inú dídùn si ogun ká