Psalms 68:31 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Jẹ́ kí àwọn ikọ̀ wá láti Ijipti, kí àwọn ará Kuṣi tẹ́wọ́ adura sí Ọlọrun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ-alade yio ti Egipti jade wá; nisisiyi ni Etiopia yio nà ọwọ rẹ̀ si Ọlọrun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ aládé yóò wá láti Éjíbítì; Jẹ́ kí Etiópíà na ọwọ́ Rẹ̀ sí Ọlọ́run.