Psalms 69:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Yọ mí ninu irà yìí, má jẹ́ kí n rì, gbà mí kúrò lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Yọ mi kuro ninu ẹrẹ̀, má si ṣe jẹ ki emi ki o rì: gbigbà ni ki a gbà mi lọwọ awọn ti o korira mi, ati ninu omi jijìn wọnni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbá mí kúrò nínú ẹrẹ̀, Má ṣe jẹ́ kí ń rí; gbà mí lọ́wọ́ àwọn tí o korìíra mi, kúrò nínú ibú omi.