Psalms 69:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Má ṣe fi ojú pamọ́ fún èmi, iranṣẹ rẹ, nítorí tí mo wà ninu ìdààmú, yára dá mi lóhùn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki o má si ṣe pa oju rẹ mọ́ kuro lara iranṣẹ rẹ: emi sa wà ninu ipọnju; yara, da mi lohùn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Má ṣe pa ojú Rẹ mọ́ fún ọmọ ọ̀dọ̀ Rẹ: yára dá mi lóhùn, nítorí mo wà nínú ìpọ́njú.