Psalms 69:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ̀gàn ti mú kí inú mi bàjẹ́, tóbẹ́ẹ̀ tí ọkàn mi rẹ̀wẹ̀sì mò ń retí àánú ṣugbọn kò sí; mò ń retí olùtùnú, ṣugbọn n kò rí ẹnìkan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹgan ti bà mi ni inu jẹ; emi si kún fun ikãnu: emi si woye fun ẹniti yio ṣãnu fun mi, ṣugbọn kò si; ati fun awọn olutunu, emi kò si ri ẹnikan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ̀gàn ba ọkàn mi jẹ́ wọ́n fi mí sílẹ̀ láìsí ìrànlọ́wọ́ Mo ń wá aláàánú, ṣùgbọ́n kò sí, mo ń wá olùtùnú, Ṣùgbọ́n n kò rí ẹnìkankan.