Psalms 69:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Iwọ ni wọ́n sọ di oúnjẹ fún mi, nígbà tí òùngbẹ sì ń gbẹ mí, ọtí kíkan ni wọ́n fún mi mu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn fi orõro fun mi pẹlu li ohun jijẹ mi; ati li ongbẹ mi nwọn fun mi li ọti kikan ni mimu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n fi òróró fún mi pẹ̀lú ohun jíjẹ mi, àti ní òungbẹ mi, wọn fi ọtí kíkan fún mi.