Psalms 69:28 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Pa orúkọ wọn rẹ́ kúrò ninu ìwé ìyè; kí á má sì kọ orúkọ wọn mọ́ ti àwọn olódodo.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nù wọn kuro ninu iwe awọn alãye, ki a má si kọwe wọn pẹlu awọn olododo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jẹ́ kí a yọ wọ́n kúrò nínú ìwé ìyè kí á má kà wọn pẹ̀lú àwọn olódodo.