Psalms 69:34 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Jẹ́ kí ọ̀run ati ayé kí ó yìn ín, òkun ati gbogbo ohun tí ó ń rìn káàkiri ninu wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jẹ ki ọrun on aiye ki o yìn i, okun ati ohun gbogbo ti nrakò ninu wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí ọ̀run àti ayé yìn ín, òkun àti àwọn tí ń gbé inú Rẹ̀,