Psalms 69:35 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí Ọlọrun yóo gba Sioni là; yóo sì tún àwọn ìlú Juda kọ́; àwọn iranṣẹ rẹ̀ yóo máa gbé inú rẹ̀, yóo sì di tiwọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoriti Ọlọrun yio gbà Sioni là, yio si kọ́ ilu Juda wọnni: ki nwọn ki o le ma gbe ibẹ, ki nwọn ki o le ma ni i ni ilẹ-ini.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí tí Ọlọ́run yóò gba Síónì là yóò sì tún àwọn ìlú Júdà wọ̀nyí kọ́. Kí wọn ó lè máa gbé ibẹ̀, kí wọn ó lè máa níi ni ilẹ̀ ìní