Psalms 69:36 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ àwọn iranṣẹ rẹ̀ yóo jogún rẹ̀; àwọn tí ó fẹ́ràn orúkọ rẹ̀ yóo sì máa gbé inú rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iru-ọmọ awọn iranṣẹ rẹ̀ pẹlu ni yio ma jogun rẹ̀: awọn ti o si fẹ orukọ rẹ̀ ni yio ma gbe inu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ ọmọ ọ̀dọ̀ ni yóò máa jogún Rẹ̀, àwọn ti ó fẹ́ orúkọ Rẹ ní yóò máa gbé inú Rẹ̀.