Psalms 69:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn tí ó kórìíra mi láìnídìí pọ̀, wọ́n pọ̀ ju irun orí mi lọ. Àwọn tí ó fẹ́ pa mí run lágbára. Àwọn ọ̀tá mi ń parọ́ mọ́ mi, àwọn nǹkan tí n kò jí ni wọ́n ní kí n fi dandan dá pada.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ti o korira mi lainidi jù irun ori mi lọ: awọn ti nṣe ọta mi laiṣẹ, ti iba pa mi run, nwọn lagbara: nigbana ni mo san ohun ti emi kò mu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tí ó kórìíra mi láìnídìí wọn ju irun orí mi; lọ púpọ̀ ni àwọn ọ̀tá mi láìnídìí, àwọn tí ń wá láti pa mí run A fi ipá mú mi láti san ohun tí èmi kò jí.