Psalms 69:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Má tìtorí tèmi dójúti àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé ọ, OLUWA Ọlọrun àwọn ọmọ ogun, má sì tìtorí mi sọ àwọn tí ń wá ọ di ẹni àbùkù, Ọlọrun Israẹli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa, Ọlọrun awọn ọmọ-ogun, máṣe jẹ ki oju ki o tì awọn ti o duro de ọ nitori mi: máṣe jẹ ki awọn ti nwá ọ ki o damu nitori mi, Ọlọrun Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Má ṣe dójú tì àwọn tí ó ní ìrètí nínú Rẹ nítorí mi, OLÚWA, Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun; Má ṣe jẹ́ kí àwọn tó ń wá ọ dààmú nítorí mi, Ọlọ́run Ísírẹ́lì.