Psalms 7:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA, Ọlọrun mi, ìwọ ni mo sá di; gbà mí là, kí o sì yọ mí lọ́wọ́ àwọn tí ń lépa mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
OLUWA, Ọlọrun mi, iwọ ni mo gbẹkẹ mi le: gbà mi lọwọ gbogbo awọn ti nṣe inunibini si mi, ki o si yọ mi kuro.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA Ọlọ́run mi, ààbò mi wà nínú Rẹ; gba mí là kí o sì tú mí sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn tó ń lé mi,