Psalms 7:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
jẹ́ kí ọ̀tá ó lé mi bá, kí ó tẹ̀ mí pa, kí ó sì bo òkú mi mọ́ ilẹ̀ẹ́lẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jẹ ki ọta ki o ṣe inunibini si ọkàn mi, ki o si mu u; ki o tẹ̀ ẹmi mi mọlẹ, ki o si fi ọlá mi le inu ekuru.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà jẹ́ kí ọ̀ta mi le mi kí wọn sì mú mi; jẹ́ kí òun kí ó tẹ ẹ̀mí mi mọ́lẹ̀ kí wọn sì mú mi sùn nínú eruku. Sela