Psalms 7:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA, fi ibinu dìde! Gbéra, kí o bá àwọn ọ̀tá mi jà ninu ìrúnú wọn; jí gìrì, Ọlọrun mi; ìwọ ni o ti fi ìlànà òdodo lélẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dide Oluwa, ni ibinu rẹ! gbé ara rẹ soke nitori ikannu awọn ọta mi: ki iwọ ki o si jí fun mi si idajọ ti iwọ ti pa li aṣẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Dìde, OLÚWA, nínú ìbínú Rẹ; dìde lòdì sí ìrunú àwọn ọ̀ta mi. Jí, Ọlọ́run mi; kéde òdodo.