Psalms 70:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Jẹ́ kí ojú ti gbogbo àwọn tí wọn fẹ́ gba ẹ̀mí mi kí ìdàrúdàpọ̀ bá wọn; jẹ́ kí á lé àwọn tí ń wá ìpalára mi pada sẹ́yìn, kí wọn sì tẹ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki oju ki o tì awọn ti nwá ọkàn mi, ki nwọn ki o si dãmu: ki nwọn ki o si pada sẹhin, ki a si dãmu awọn ti nwá ifarapa mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí àwọn tí ń wá ọkàn mi kí a dojú tì wọ́n, kí wọn sì dààmú; kí àwọn tó ń wá ìparun mi yí ẹ̀yìn padà nínú ìtìjú.