Psalms 70:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kí gbogbo àwọn tí ń wá ọ máa yọ̀ nítorí rẹ, kí inú wọn sì máa dùn, kí àwọn tí ó fẹ́ràn ìgbàlà rẹ máa wí nígbà gbogbo pé, “Ọlọrun tóbi!”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki gbogbo awọn ti nwá ọ ki o ma yọ̀, ki inu wọn ki o si ma dùn nipa tirẹ: ki iru awọn ti o si fẹ igbala rẹ ki o ma wi nigbagbogbo pe, Ki a gbé Ọlọrun ga!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n kí àwọn tí o ń wà ọ ó máa yọ̀ kí inú wọn kí ó sì máa dùn nípa Rẹ, kí àwọn tí ó ń fẹ́ ìgbàlà Rẹ máa wí pé, “Jẹ́ kí a gbé Ọlọ́run ga!”