Psalms 71:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí pé àwọn ọ̀tá mi ń sọ̀rọ̀ mi, àwọn tí ń lépa ẹ̀mí mi ti pàmọ̀ pọ̀,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori awọn ọta mi nsọ̀rọ si mi; awọn ti nṣọ ọkàn mi si gbimọ̀ pọ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí àwọn ọ̀tá mi ń sọ̀rọ̀ òdì sí mi àwọn tí wọn dúró láti pa mí gbìmọ̀ pọ̀