Psalms 71:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
N óo máa ṣírò iṣẹ́ rere rẹ, n óo máa ròyìn iṣẹ́ ìgbàlà rẹ tọ̀sán-tòru, nítorí wọ́n pọ̀ tóbẹ́ẹ̀ tí n kò lè mọ iye wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹnu mi yio ma fi ododo rẹ ati igbala rẹ hàn li ọjọ gbogbo; emi kò sa mọ̀ iye rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹnu mí yóò sọ nípa ti òdodo Rẹ, ti ìgbàlà Rẹ ni gbogbo ọjọ́ lóòtọ́, èmi kò mọ́ iye Rẹ̀.