Psalms 71:18 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nisinsinyii tí mo ti dàgbà, tí ewú sì ti gba orí mi, Ọlọrun, má kọ̀ mí sílẹ̀, títí tí n óo fi ròyìn iṣẹ́ ńlá rẹ, àní, iṣẹ́ agbára rẹ, fún gbogbo àwọn ìran tí ń bọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Pẹlupẹlu, nigbati emi di arugbo tan ti mo hewu, Ọlọrun máṣe kọ̀ mi; titi emi o fi fi ipá rẹ hàn fun iran yi, ati agbara rẹ fun gbogbo awọn ara ẹ̀hin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Pẹ̀lúpẹ̀lú, nígbà tí ẹnu di arúgbó tán tí mo sì hewú, Má ṣe kọ̀ mí sílẹ̀, Ọlọ́run títí tí èmi o fi ipá re han ìran yìí àti agbára Rẹ fún gbogbo àwọn ará ẹ̀yìn, sọ ti agbára sí ìran tí ń bọ̀ agbára Rẹ̀ fún àwọn tí yóò wá.