Psalms 71:24 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹnu mi yóo ròyìn iṣẹ́ rẹ tọ̀sán-tòru, nítorí a ti ṣẹgun àwọn tí ó fẹ́ pa mí lára, a sì ti dójú tì wọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ahọn mi pẹlu yio si ma sọ̀rọ ododo rẹ titi li ọjọ gbogbo: nitoriti nwọn dãmu, a si doju ti awọn tí nwá ifarapa mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ahọ́n mí yóò sọ ti òdodo Rẹ ní gbogbo ọjọ́, fún àwọn tí ó fẹ́ pa mí lára a sì dójúti àwọn tí ń wá ìdààmú mi.