Psalms 71:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ìwọ ni mo gbára lé láti inú oyún; ìwọ ni o mú mi jáde láti inú ìyá mi. Ìwọ ni n óo máa yìn nígbà gbogbo.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọwọ rẹ li a ti fi gbé mi duro lati inu wá: iwọ li ẹniti o mu mi jade lati inu iya mi wá: nipasẹ rẹ ni iyìn mi wà nigbagbogbo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mo gbẹ́kẹ̀lé ọ láti ìgbà ìbí mi; Ìwọ mu mi jáde láti inú ìyá mi wá èmi ó máa yìn ọ títí láé