Psalms 72:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọba Taṣiṣi ati àwọn ọba erékùṣù gbogbo yóo máa san ìṣákọ́lẹ̀ fún un; àwọn ọba Ṣeba ati ti Seba yóo máa mú ẹ̀bùn wá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọba Tarṣiṣi, ati ti awọn erekuṣu yio mu ọrẹ wá: awọn ọba Ṣeba ati ti Seba yio mu ẹ̀bun wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọba Táṣíṣì àti tí erékùṣù wọn yóò mú ọrẹ wá fún un; àwọn ọba Ṣéba àti Síbà wọn o mú ẹ̀bùn wá fún-un.