Psalms 72:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbogbo àwọn ọba yóo máa wólẹ̀ fún un; gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè yóo sì máa sìn ín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitõtọ, gbogbo awọn ọba ni yio wolẹ niwaju rẹ̀: gbogbo awọn orilẹ-ède ni yio ma sìn i.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo ọba yóò tẹríba fún-un àti gbogbo orílẹ̀ èdè yóò sìn ín.