Psalms 72:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí pé a máa gba talaka tí ó bá ké pè é sílẹ̀; a sì máa gba àwọn tí ìyà ń jẹ sílẹ̀, ati àwọn tí kò ní olùrànlọ́wọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori yio gbà alaini nigbati o ba nke: talaka pẹlu, ati ẹniti kò li oluranlọwọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí yóò gba àwọn aláìní nígbà tí ó bá ń ké, tálákà àti ẹní tí kò ni olùrànlọ́wọ́.