Psalms 72:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ̀mí rẹ̀ yóo gùn, a óo máa fi wúrà Ṣeba ta á lọ́rẹ, a óo máa gbadura fún un nígbà gbogbo; a óo sì máa súre fún un tọ̀sán-tòru.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On o si yè, on li a o si fi wura Ṣeba fun: a o si ma gbadura fun u nigbagbogbo: lojojumọ li a o si ma yìn i.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Yóò sì yè pẹ́! A ó sì fún un ní wúrà Ṣébà. Àwọn ènìyàn yóò sì máa gbàdúrà fún-un nígbà gbogbo kí a sì bùkún fún-un lójojúmọ́.