Psalms 73:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ wò ó! Ayé àwọn eniyan burúkú nìwọ̀nyí; ara dẹ̀ wọ́n nígbà gbogbo, ọrọ̀ wọn sì ń pọ̀ sí i.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kiyesi i, awọn wọnyi li alaìwa-bi-ọlọrun, ẹniti aiye nsan, nwọn npọ̀ li ọrọ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí àwọn ènìyàn búburú ṣe rí nìyí ènìyàn asán, wọn ń pọ̀ ní ọrọ̀.