Psalms 73:28 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ní tèmi o, ó dára láti súnmọ́ Ọlọrun; mo ti fi ìwọ OLUWA Ọlọrun ṣe ààbò mi, kí n lè máa ròyìn gbogbo iṣẹ́ rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn o dara fun mi lati sunmọ Ọlọrun: emi ti gbẹkẹ mi le Oluwa Ọlọrun, ki emi ki o le ma sọ̀rọ iṣẹ rẹ gbogbo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ní ti èmi, ó dára láti súnmọ́ Ọlọ́run Èmi ti fi OLÚWA Ọlọ́run ṣe ààbò mi; Kí èmi ó lè máa sọ̀rọ̀ iṣẹ́ Rẹ.