Psalms 73:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí mò ń ṣe ìlara àwọn onigbeeraga nígbà tí mo rí ọrọ̀ àwọn eniyan burúkú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ti emi ṣe ilara si awọn aṣe-fefe, nigbati mo ri alafia awọn enia buburu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí èmi ń ṣe ìlara àwọn tó ń ṣeféfé nígbà tí mo bá rí ọlá àwọn ènìyàn búburú.