Psalms 73:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọn kì í ní wahala bí àwọn ẹlòmíràn; ìyọnu tíí dé bá àwọn ẹlòmíràn kì í dé ọ̀dọ̀ wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn kò ni ipin ninu iyọnu enia; bẹ̃ni a kò si wahala wọn pẹlu ẹlomiran.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn kò ní ìpín nínú àjàgà tó ń ṣẹlẹ̀ si ènìyàn; a kò pọ́n wọn lójú nípa ẹlomíràn.