Psalms 73:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà, wọn á kó ìgbéraga bọ ọrùn bí ẹ̀gbà, wọn á fi ìwà ipá bora bí aṣọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina ni igberaga ṣe ká wọn lọrun bi ẹ̀wọn ọṣọ́; ìwa-ipa bò wọn mọlẹ bi aṣọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìgbéraga ni ọ̀ṣọ́ ọrùn wọn; ìwà ìpá bò wọ́n mọ́lẹ̀ bí aṣọ.