Psalms 73:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n ń pẹ̀gàn eniyan, wọ́n ń sọ̀rọ̀ pẹlu ìlara; wọ́n sì ń fi ìgbéraga halẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn nṣẹsin, nwọn si nsọ̀rọ buburu niti inilara: nwọn nsọ̀rọ lati ibi giga.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn ń ṣẹ̀sín, wọn sì ń sọ̀rọ̀ òdì níti ìnilára, wọn ń sọ̀rọ̀ láti ibi gíga.