Psalms 74:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ranti ìjọ eniyan rẹ tí o ti rà ní ìgbà àtijọ́, àwọn ẹ̀yà tí o rà pada láti fi ṣe ogún tìrẹ; ranti òkè Sioni níbi tí o ti ń gbé rí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ranti ijọ enia rẹ ti iwọ ti rà nigba atijọ; ilẹ-ini rẹ ti iwọ ti rà pada; òke Sioni yi, ninu eyi ti iwọ ngbe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Rántí àwọn ènìyàn tí ìwọ ti rà nígbà àtijọ́, ẹ̀yà ilẹ̀ ìní Rẹ, tí ìwọ ti ràpadà Òkè Síónì, níbi tí ìwọ ń gbé.