Psalms 74:23 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Má gbàgbé ariwo àwọn ọ̀tá rẹ; àní, igbe àwọn tí ó gbógun tì ọ́, tí wọn ń ké láìdá ẹnu dúró.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Máṣe gbagbe ohùn awọn ọta rẹ: irọkẹ̀kẹ awọn ti o dide si ọ npọ̀ si i nigbagbogbo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Má ṣe gbàgbé ohun àwọn ọ̀tá Rẹ, bíbú àwọn ọ̀tá Rẹ, tí ó ń pọ̀ síi nígbà gbogbo.