Psalms 74:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Rìn káàkiri kí o wo bí gbogbo ilẹ̀ ti di ahoro, wo bí ọ̀tá ti ba gbogbo nǹkan jẹ́ ninu ibi mímọ́ rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbé ẹsẹ rẹ soke si ahoro lailai nì; ani si gbogbo eyiti ọta ti fi buburu ṣe ni ibi-mimọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Yí ẹṣẹ̀ Rẹ̀ padà sí ìparun ayérayé wọn, gbogbo ìparun yìí tí ọ̀ta ti mú wá sí ibi mímọ́.