Psalms 74:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọ̀tá rẹ bú ramúramù ninu ilé ìsìn rẹ; wọ́n ta àsíá wọn gẹ́gẹ́ bí àmì ìṣẹ́gun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọta rẹ nke ramu-ramu lãrin ijọ enia rẹ; nwọn gbé asia wọn soke fun àmi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọ̀tá Rẹ ń bú ramú-ramù láàrin ìja ènìyàn Rẹ, wọ́n ń gbé Àṣìá wọn sókè fún àmì;