Psalms 74:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbogbo pákó tí a fi dárà sí ara ògiri ni wọ́n fi àáké ati òòlù fọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn nisisiyi iṣẹ ọnà finfin ni nwọn fi akeke ati òlu wó lulẹ pọ̀ li ẹ̃kan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n nìsìnsìn yìí iṣẹ́ ọnà fínfín ní wọn fi àáké òòlù wó lulẹ̀ ní ẹ̀ẹ̀kan náà