Psalms 76:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún OLUWA Ọlọrun rẹ, kí o sì mú un ṣẹ, kí gbogbo àwọn tí ó yí i ká mú ẹ̀bùn wá fún ẹni tí ó yẹ kí á bẹ̀rù.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ ṣe ileri ifẹ, ki ẹ si san a fun Oluwa, Ọlọrun nyin: jẹ ki gbogbo awọn ti o yi i ka ki o mu ẹ̀bun wá fun ẹniti a ba ma bẹ̀ru.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jẹ́ ẹ̀jẹ́ sí OLÚWA Ọlọ́run Rẹ kí o sì mú-un ṣẹ; kí gbogbo àwọn tí ó yíi ká mú ẹ̀bùn wá fún ẹni tí o tọ́ láti bẹ̀rù.