Psalms 76:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
A gba ìkógun lọ́wọ́ àwọn akikanju, wọ́n sun oorun àsùn-ùn-jí; àwọn alágbára kò sì le gbé ọwọ́ láti jà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A kó awọn alaiya lile ni ikogun, nwọn ti sùn orun wọn, gbogbo ọkunrin alagbara kò si ri ọwọ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn akíkanjú ọkùnrin A kó àwọn akíkanjú ogun ní ìkógun wọn sún oorun ìgbẹ̀yìn wọn; kò sí ọ̀kan nínú àwọn ajagun tó lè gbé ọwọ́ Rẹ̀ sókè.