Psalms 76:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nípa ìbáwí rẹ, Ọlọrun Jakọbu, ati ẹṣin, ati ẹni tó gun ẹṣin, gbogbo wọn ló ṣubú lulẹ̀, tí wọn kò sì lè mira.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nipa ibawi rẹ, Ọlọrun Jakobu, ati kẹkẹ́-ogun ati ẹṣin sun orun asunkú.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ìfìbú Rẹ, Ọlọ́run Jákọ́bù, àwọn ẹsin àti kẹ̀kẹ́ ogun sì dúbúlẹ̀ ṣíbẹ̀.