Psalms 76:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
nígbà tí Ọlọrun dìde láti gbé ìdájọ́ kalẹ̀, láti gba gbogbo àwọn tí à ń nilára láyé sílẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati Ọlọrun dide si idajọ, lati gbà gbogbo ọlọkan-tutu aiye là.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí, ìwọ Ọlọ́run, bá dìde láti ṣe ìdájọ́, láti gba àwọn ẹni ìnílára ilẹ̀ náà. Sela