Psalms 77:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
O ti fi agbára rẹ gba àwọn eniyan rẹ là; àní, àwọn ọmọ Jakọbu ati Josẹfu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ li o ti fi apá rẹ rà awọn enia rẹ pada, awọn ọmọ Jakobu ati Josefu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Pẹ̀lú ọwọ́ agbára Rẹ ni ìwọ ra àwọn ènìyàn padà, àwọn ọmọ Jákọ́bù àti Jósẹ́fù. Sela