Psalms 77:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí omi òkun rí ọ, Ọlọrun, àní, nígbà tí omi òkun fi ojú kàn ọ́, ẹ̀rù bà á; ibú omi sì wárìrì.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Omi ri ọ, Ọlọrun, omi ri ọ, ẹ̀ru bà wọn: nitõtọ ara ibú kò balẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí àwọn omi rí Ọlọ́run, nígbà tí àwọn omi rí ọ, ẹ̀rù bà wọ́n, nítòótọ́ ara ibú kò balẹ̀.