Psalms 77:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ní ọjọ́ ìpọ́njú mi, mo wá OLUWA; ní òru, mo tẹ́wọ́ adura láìkáàárẹ̀, ṣugbọn n kò rí ìtùnú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Li ọjọ ipọnju mi emi ṣe afẹri Ọlọrun: ọwọ mi nnà li oru, kò si rẹ̀ silẹ: ọkàn mi kọ̀ ati tù ninu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí mo wà nínú ìpọ́njú, mo wá OLÚWA; ní òru ni mo na ọwọ́ mi jáde ní àìkáárẹ̀ ọkàn mí sì kọ láti tùú nínú.