Psalms 78:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó fi ìkùukùu ṣe atọ́nà wọn ní ọ̀sán, ó fi ìmọ́lẹ̀ iná tọ́ wọn sọ́nà ní gbogbo òru.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Li ọsan pẹlu o fi awọsanma ṣe amọna wọn, ati li oru gbogbo pẹlu imọlẹ iná.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ọ̀ṣán ó fi ìkúùku àwọsánmọ̀ ṣe amọ̀nà wọn àti ní gbogbo òru pẹ̀lú, ìmọ̀lẹ̀ ìná.