Psalms 78:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Sibẹsibẹ wọn ò dẹ́kun ẹ̀ṣẹ̀ dídá; wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí Ọ̀gá Ògo ninu aṣálẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si tún ṣẹ̀ si i; ni ṣiṣọtẹ si Ọga-ogo li aginju.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n sì tún tẹ̀ṣíwájú láti dẹ́sẹ̀ sí i ní ìsọ̀tẹ̀ sí Ọ̀gá ògo ní àgìnjú.