Psalms 78:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lóòótọ́ ó lu òkúta tí omi fi tú jáde, tí odò sì bẹ̀rẹ̀ sí ṣàn. Ṣé ó lè fún wa ní òkèlè pẹlu, àbí ó lè pèsè ẹran fún àwọn eniyan rẹ̀?”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Wò o! o lù apata, omi si tú jade, iṣàn-omi si kún pupọ; o ha le funni li àkara pẹlu? o ha le pèse ẹran fun awọn enia rẹ̀?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí ó lu àpáta, omi tú jáde, odò sì ṣàn lọ́pọ̀lọpọ̀ ṣùgbọ́n òun ha lè fún wa lóúnjẹ ó ha le pèṣè ẹran fún àwọn ènìyàn Rẹ̀”