Psalms 78:21 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà nígbà tí OLUWA gbọ́, inú bí i; iná mọ́ ìdílé Jakọbu, inú OLUWA sì ru sí àwọn ọmọ Israẹli;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina, Oluwa gbọ́ eyi, o binu: bẹ̃ni iná ràn ni Jakobu, ibinu si ru ni Israeli;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí OLÚWA gbọ́ wọn, ó bínú gidigidi; iná Rẹ̀ sọ̀kalẹ̀ sí Jákọ́bù, ìbínú Rẹ̀ sì rú sí Ísírẹ́lì,